Review series Episodes(Review Ministries)
Review Ministries
0
This podcast focuses on nurturing a new life in Christ and deepening one's relationship with God day by day. It offers spiritual guidance and encouragement for personal growth in faith. The episodes are produced by Review Ministries and are freely accessible to all. Music played in the episodes is credited to its original creators.
Epizódok
-
Ètò Èro Ìjìnlè Fún Ìrìnná{v}-{Èro Ijinle Ti Igbalode} 30.03.2025 22pD'arapo mo wa l'ati tesiwaju wiwo oro Olorun (bibeli) gege bi ipese itosona ti igbalode ti a gbe kale fun Kristieni l'oni nigbati a o ma ko eko pata l'ati inu iwe awon oba keji(2 kings) ati Nehemiah🔎📖📖📖
-
Ètò Èro Ìjìnlè Fún Ìrìnnà {¡v}-{Èro Ījìnlè Ti Ìgbàlódé} 16.03.2025 16pBi nkan ko ba je ti atijo/igbaani, a si je ti igbalode sugbon kini eto ero irinna ti igbalode ti Olorun pese fun wa loni?🤔. D'arapo mo wa fun eko pataki yi...📖📖📖🔎🔎🔎
-
Ètò Èro Ìjìnlè Fún Ìrìnnà{¡¡¡}-{Èro Ìjìnlè Ti Ìgbàanì} 02.03.2025 17pOhun kan ni Israeli ni l'ati se bi won ba fe ki 'ero ijinle ti igbaani' mu won gunle si ebute yiyanju eyun ni ile ileri won. D'arapo mo wa lowuro yi nigbati a n tesiwaju wiwo bi ero oun ti n sise📖👩💻👨💻🧑💻🧑💻👨💻👩💻...
-
Spiritual Starvation And Dehydration {¡} 01.03.2025 20pJoin us for a time in God's presence as we search the scripture 📖 in depth for answers. May our eyes be opened to see and our hearts to wisdom 🙏🏾🙏🏾. Song played: Let your living water by vinesong. Contact us via email: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082
-
Ètò Èro Ìjìnlè Fún Ìrìnnà{¡¡}-{Èro Ìjìnle Ti Ìgbàanì} 09.02.2025 18pKini iru ero ijinle ti o dari irin-ajo awon ara igbaani? Bawo ni ero oun ti n şise?🤔...D'arapo mo wa fun itesiwaju eko yi...👩💻👨💻🧑💻🧑💻👨💻👩💻👨💻🧑💻👩💻....
-
Support System {¡¡} 08.02.2025 18pToday, let's look at the role of Aaron and Hur as a support system for Moses/all Israel that brought about the defeat of their enemy, the Amalekites. Exodus 17: 8-13....join us and let's study👩💻👨💻🧑💻🧑💻👩💻🧑💻👨💻👩💻....
-
Ètò Èro Ìjìnlè Fún Ìrìnnà{¡} 26.01.2025 15pNje o mo ohun ti èro yi je ati bi o ti n şişé? D'arapo mo wa fun alaye kikun l'ori re nigbati a o ka iwe orin-Dafidi l'ati ki alaye wa l'ehin....(Psalm 16:8&9)....👨💻👩💻🧑💻🧑💻👩💻👨💻👩💻👨💻🧑💻
-
Support System {¡} 25.01.2025 22pJoin us friends as we start our study and series with an interesting topic. Who is/are support systems?🤔. We'll be reading from the book of Esther 3&4... Study with us🧑💻👩💻👨💻👨💻👩💻🧑💻👩💻👨💻🧑💻.....
-
Eto Pataki Fun Idupe Odun Ati Adura 12.01.2025 16pD'arapo mo wa òré fun idupe ati adura nigbati a o maa yin Olorun pelu orin ope, ti a o si tun fi irin-ajo wa le e l'owo fun odun titun. E je ki a gbadura;🙏🏾🙏🏾🙏🏾
-
Thanksgiving And Prayer Session 11.01.2025 18pHappy New Year! 🎶🎵🎼🙏🏾....Join us as we give thanks to God for the outpour of his blessings on us and also to commit the year unto him....Thanks for staying with us friends, we do not take your time and love for granted. Thank you!🙏🏾🙏🏾🙏🏾
-
Eto Pataki Fun Keresimesi 25.12.2024 28pA ku odun, a ku iyedun. Odun a y'abo fun wa. Oju wa yoo si ma r'odun l'oruko Jesu Kristi. Amin!🙏🏾....🎄🎼🎵🎶
-
Lost In Festivity 25.12.2024 19pWe invite you this morning to join us for special Christmas episode as we put CHRIST at the centre of our celebration. Happy Christmas Reviewers!🎄🎄🎼🎶🎵
-
Åròyé Àti Àwon Aláròye{¡¡} 15.12.2024 16pE je ki a wo imoran ti Poolu ati Solomoni gba wa ninu iwe Filipi ati iwe Owe, ki a wa to tesiwaju l'ati wo ida keji aroye/irahun ninu iwe Orin-Dafidi ori aadota {Psalm 50:14&15}. A ku ipalemo odun, yoo ba wa l'ayo...🙏🏾 Kan si wa l'ori; reviewseries20@gmail.com/ +447417522082
-
Hello! Have You Got Room? 14.12.2024 10pHave you ever thought about what the the first Christmas was like?🤔....Because it was nothing like what we celebrate today...it was about Mary and Joseph knocking on doors to see who had a room to birth the saviour, Jesus Christ. Today, the King of glory continues to knock on the door of people's heart to see who's got a room for him in their heart. Have you got one in yours?
-
Àròyé Àti Àwon Aláròyé{¡} 01.12.2024 19pNje o ti e je eniyan tii ma s'aroye? Bi o ba fe mo, gbiyanju l'ati d'arapo mo wa fun eko yi ki o le mo ohun ti aroye tumo si ati pe boya o ti tibe d'eşe🤔....🧑💻👨💻👩💻👩💻🧑💻👨💻... Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082
-
The Circumcised Heart {¡v}2 Corinthians 5:17 30.11.2024 18pWhat makes the believer's new life possible is the change that happens within by the power of the Holy Spirit. He works on the inward(heart) part of the believer and that, gradually works it's way out. But what exactly does the circumcised heart looks like?🤔....Come with us to the book of Acts as we round up this series....🧑💻👨💻👩💻👨💻👩💻🧑💻 Contact us via email: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082 You can also leave a comment in the comment section of the app.
-
Wíwá Ònà Àbáyo Sí Ìpàdánù Fún Ìpòñgbe Ti Èmí{x} 10.11.2024 19pA o mu eko yi wa s'opin l'oni nigbati a o maa wo: "jije omo agbo ile igbagbo" fun igba ikehin....d'arapo mo wa...🧑💻👩💻👨💻👩💻👨💻🧑💻👨💻🧑💻👩💻.... Kan si wa l'ori: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082
-
The Circumcised Heart {¡¡¡}...Deuteronomy 10:16 09.11.2024 20pToday, we go into the gospels to see how Jesus used the concept of farming to describe a fruitful or productive Christian life as we relate it to the heart of the believer...John 15:1-4,....5.....👩💻👨💻🧑💻👨💻👩💻🧑💻🧑💻👩💻👨💻 Contact us via: reviewseries20@gmail.com/ +447417522082
-
Wíwá Ònà Àbáyo Sí Ìpàdánù Fún Ipongbe Ti Èmí{¡x} Luku 24:49 27.10.2024 18pA n tesiwaju l'ati maa wo awon anfaani to wa ninu jije omo agbo ile igbagbo nigbati a o maa ka ise awon aposteli(Acts 1:12-14, 2:1-4) ni wiwo bi awon omo ehin ti gba ileri naa ti a se fun won ni kikun....👩💻👨💻🧑💻🧑💻👨💻👨💻🧑💻👩💻🧑💻👨💻👩💻....
-
The Circumcised Heart {¡¡} 26.10.2024 20pLet's go back to Romans chapter 2 to see how the old testament laws and beliefs relate to chriatianity as explained by Paul. Romans 2:17-25,29. Is Paul talking to or about you and i??🤔....🧑💻👩💻👨💻👩💻👨💻🧑💻👨💻🧑💻👩💻.... You can reach us on: +447417522082/ reviewseries20@gmail.com.